Skip to main content

Káàbọ̀!

Ìlànà Ilé-ìwé Ìjọba Agbègbè Baltimore (BCPS) jẹ́ ẹkùn ilé-ìwé kẹẹ̀ta tí ó tóbi jùlọ ní Maryland pẹ̀lú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tó ju 115,000 lọ ní ilé-ìwé 175, ètò, àti gbọ̀ngán. Láti wá àlàyé nípa ilé-ìwé ọmọ rẹ, lo irinṣẹ́ ìṣàwárí ti ilé-ìwé láti ṣàwárí ilé-ìwé náà àti ojúlé wẹ́ẹ̀bù ti ilé-ìwé

Àwọn Ìsọdọ̀tun

Ìkẹ́kọ̀ọ́ orí ayélujára

Àwọn akẹ́kọ̀ọ́, wọlé sínú BCPS One fún ìtọ́ni.

Oúnjẹ Kí o sì Forúkọsílẹ̀ fún ilé-ìwé

Àtìlẹ́yìn ìmọ̀-ẹ̀rọ

Àtìlẹ́yìn ìráyèsí èdè

 • Ìrànlọ́wọ́ èdè nípasẹ̀ fóònù
 • Iṣẹ́ ògbùfọ̀
 • Ohùn orí ago Ìbásọ̀rọ̀ Ilé-ìwé Ẹbí ESOL

Ayélujára ọ̀fẹ́

Èdà Ètò Àtúnsí fún Ìgba Òjò 2020

 • Ìtọ́ni olùkọ́ tí ń lọ lọ́wọ́
 • Àwọn ẹ̀kọ́ pẹ̀lú yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́ kíkún
 • Ìkẹ́kọ̀ọ́ ìmọ̀lára-ojúlùmọ̀
 • Ìtọ́ni ọ̀wọ́ kékeré bó ti nílò
 • Ìṣesí olómìnira
 • Iṣẹ́-ọnà, Eré Ìdárayá, Orin àti Kíkàwé (alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀)
 • Àtìlẹ́yìn ẹnìkọ̀ọ̀kan láti ọ̀dọ̀ olùdámọ̀ràn ilé-ìwé
 • Àwọn àkókò ìsinmi

Ṣíṣe àbẹ̀wò sí BCPS nípasẹ̀ ètò ìpàdé

Ìlera àti ààbò
Bí o ti le túmọ̀ àwọn ojúlé wẹ́ẹ̀bù Èdè Gẹ̀ẹ́sì
Aago ìpè Agbègbè Baltimore COVID-19: 410-887-3816
Àwọn Ilé-iṣẹ́ fún Ìdènà àti Ìdarí Àrùn
Ìjọba Agbègbè Baltimore: àwọn ìṣẹ̀lẹ̀, àmúyẹ, ìdánwò ọ̀fẹ́, aago ìpè, àti àwọn àmúlò oúnjẹ
Ẹka Isẹ́ Ìlera ti Maryland

Àwọn Káàdì Ìròyìn àti Àwọn Ìròyìn Ìtẹ̀síwájù

Àwọn Ọ̀nà-ìsopọ̀ Kíá

 • Kàlẹ́ndà BCPS
 • Ile-iṣẹ́ ESOL
  Ilé-iṣẹ́ ESOL ń pèsè ìtọ́ni fún Èdè Gẹ̀ẹ́sì fún Àwọn Elédè Míràn ní alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, àárín, ipele ilé-ìwé gíga. 
 • Ibi Ìkíni Káàbọ̀ ESOL
  Ibi Ìkíni Káàbọ̀ ESOL ń ṣàyẹ̀wò àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n ń sọ èdè míràn dáradára ju Èdè Gẹ̀ẹ́sì lọ. Tí o bá ṣẹ̀ṣẹ̀ dé agbègbè náà tí ọmọ rẹ sì ń sọ èdè míràn tó yàtọ̀ sí Èdè Gẹ̀ẹ́sì, o le ní láti lọ sí Ibi Ìkíni Káàbọ̀ kí o tó forúkọsílẹ̀ ní ilé-ìwé.   

Àwọn Iṣẹ́ Ògbùfọ̀ àti Ìbánisọ̀rọ̀ Ilé-ìwé Ẹbí Elédè-méjì

Àwọn ìbánisọ̀rọ̀ Ilé-ìwé Ẹbí Elédè-méjì ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn ẹbí fún àwọn tí Èdè Gẹ̀ẹ́sì jẹ́ èdè kejì. Jọ̀wọ́ ṣàbẹ̀wò sí ojú-ewé wẹ́ẹ̀bù Ìjade Ẹbí Àgbáyé.

BCPS ń pèsè fún àwọn ilé-ìwé ati ilé-iṣẹ́ àwọn iṣẹ́ ògbùfọ̀ ní ìta ní èdè 30/èdè abẹ́lé.  Fún àlàyé ìbánisọ̀rọ̀ jọ̀wọ́ ṣàbẹ̀wò sí Ojú-ewé wẹ́ẹ̀bù Àwọn Iṣẹ́ Ogbùfọ̀.

BCPS One

BCPS One jẹ́ ohun àyíká onídíjítà tó wà nílẹ̀ nígbàkugbà, níbikíbi fún gbogbo òṣìṣẹ́, olùkọ́, akẹ́kọ̀ọ́ àti òbí BCPS.  BCPS One ń ṣàtìlẹ́yìn fún ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìtọ́ni nípa pípèsè fún àwọn aṣàmúlò ànfàní tó wà nínú ìlànà ẹ̀kọ́ nípa ìráyèsí àwọn irinṣẹ orí ayélujára, ohun àmúlò, àti ìtẹ̀síwájú akẹ́kọ̀ọ́.

Contact BCPS

Baltimore County Public Schools
6901 Charles Street
Towson, Maryland 21204
443-809-4554

Report Fraud, Waste, or Abuse

Contact Leadership

Darryl L. Williams, Ed.D.
Superintendent

E-mail Dr. Williams

Follow @BCPS_Sup

©2020 Baltimore County Public Schools. All rights reserved.

Contact BCPS

twitter facebook Instagram Vimeo flickr BCPS Now Mobile App RSS Feeds BCPS Blog

Team BCPS Newsletter
Baltimore County Public Schools
6901 Charles Street
Towson, Maryland 21204
443-809-4554

Report Fraud, Waste, or Abuse

Darryl L. Williams, Ed.D.
Superintendent

E-mail Dr. Williams

Follow @BCPS_Sup

Site Map | Accessibility

©2020 Baltimore County Public Schools. All rights reserved.